Ìṣàkóso fáìlì
	<ctrl>N | Ṣẹ̀dá mẹ́nù tuntun
	<ctrl>O | Ṣí mẹ́nù
	<ctrl>S | Ṣàfipamọ́ mẹ́nù náà
	<ctrl><shift>S | Ṣàfipamọ́ mẹ́nù náà bí…
	<ctrl>Q | Jáde kúrò nínú àtòjọ-ètò náà
Ìṣàtúnṣe (akọ́kọ́)
	<ctrl>Z | Dàpádà ìṣàtúnṣe tó kọjá
	<ctrl>Y | Ṣàtúnṣe ìṣàtúnṣe tó kọjá
	<ctrl>T | Gbé apẹka lọ sí orí
	<ctrl>minus | Gbé apẹka sókè
	<ctrl>plus | Gbé apẹka sísàlẹ̀
	<ctrl>B | Gbé apẹka lọ sí ìsàlẹ̀
	<ctrl>R | Ṣèmúkúro apẹka
	<ctrl><shift>R | Ṣèmúkúro àwọn ọmọ apẹka
Ìṣàtúnṣe (àwọn míìrán)
	<ctrl>A | Yan gbogbo àwọn apẹka tó hàn
	<ctrl>backslash | Má ṣàyàn gbogbo àwọn apẹka tó hàn
	<ctrl>E | Ṣe àfihàn
	<shift><ctrl>E | Ṣe àfihàn lójú-ọna àtúnṣe
Ìṣàwárí
	<ctrl>F | Ṣàfihàn/fipamọ́ gírìdì ìṣàwárí
	<ctrl>H | Ṣí/Tí\nwínńdò ìṣàwárí àti ìrọ́pò
Ìwò
	<shift><ctrl>X | Fẹ gbogbo àwọn apẹka
	<shift><ctrl>C | Ṣẹ́ẹ gbogbo àwọn apẹka pọ̀
Ìrànwọ́
	F1 | Ṣí/Tí\nwínńdò ìtalólobó
	<ctrl>L | Ṣí/Tí\nwínńdò àwọn àbùjá àtẹ bọ́tìnnì
	<ctrl>I | Jábọ̀ ìṣòro
	<shift><ctrl>A | Nípa
